Ibeere .WED:
Kini .WED?
Aiye oruko tuntun to o n bo no ero idaraya ni odin 2014. AdeferanAyo.wed tabi AdeferanAyo.titilailai.wed tabi AdeferanAyo-14.Feb1016.wedati pupo si…
Ni ibo ni a le lo oruko .WED lati se website igbeyawo wa?
Awon ti won ta website fun igbeyawo re. Ejo e je ki a mo ki a le fi oruko awon website igbeyawo ti o da ju ni gbogbo ilu. Won ni lati je ki took taya lo aiye orulo .WED tiwon lati se site. E ko iwe siwa ni info@atgron.wed.
- Nbọ laipẹ
Elo ni aiye oruko .WED ma je?
Atgron ma so iye ipo keji (domainname.wed) ati ipo keta (domainname.phrase.wed) oruko .WED. Rejistra nikan ni o le ta oruko .WED fun awon eyan ati pe Rejistra ni o ma so elo. Atgron fun Rejistra won ni ijuwe yii:
1. Elo fun domainname.wed (fun apere – AyoatiAde.wed)
2. Elo fun domainname.phrase.wed (fun apere – AyoatiAde.Feb2014.wed)
1. Elo fun domainname.wed (fun apere – AyoatiAde.wed)
- Odun ekan ati ikeji $80 tabi ko din l’odoodun
- Odun keta si ewa $30,000 USD tabi ko le l’odoodun
2. Elo fun domainname.phrase.wed (fun apere – AyoatiAde.Feb2014.wed)
- Odun ekan si ewa $50 tabi ko din l’odoodun
Ni ibo ni mo le ra aiye oruko .WED?
O se je ipe owo odun keta si ewa l’odoodun fun oruko .WED po ju odun ekan ati ikeji?
Pupo ninu tokotaya ma ni oruko kanaa pelu elo mi ki on ma le ra oruko ti won fe to eyan mi be ati ra .WED na fun odun mewa. Owo .WED ni ipo keta (domain.phrase.wed) le je to odun mewa ti tokotaya ba fe .WED won ju odun meji lo.
Bawo ni mo se le toju nkan ti a ko sori .WED website wa ti a ba paro oruko .WED wa ni odun meji meji?
Ko soro. Gbogbo aiye oruko ni folda ti o ni awon nkan yi. Ti igba .WED yen to tan, e ma ra .WED tuntun ki e pa oruko yen po mo faili website yin. Ti e ba ri yi se, e bi awon ti o ta aiye yi fun yin tabi ke wo FAQ won.
Ti mo ba fe oruko .WED mi ju odun meji lo nko?
E ra domainname.phrase.wed (fun apere – AyoatiAde.Feb2014.wed) fun odun mewa tabi esan owo auto l’odoodun fun odon mewa.
Kini o se je p emo le ra oiye oruko fun odun mewa?
ICANN, ile ise ti o da ijo ero araya, o le je ki eya ra aiye oruko ju odun mewa lo.
Se mo le ra estenson .WED fun ile ise mi?
Ti e ba fe oruko .WED ni ipo keji (fun apere myweddingbusiness.wed) ti e e ba fe san owo pupo odun keta si ewa, nkan meji ni e le se:
1. E di eni ti o tun oruko .WED ta lati ma san owo odun keta – ewa.
2. Ti ile ise yin ba ta $3 million tabi ko din l’odoodun, e le parapo pelu Atgron Small Business program leyin odun keji. Ile ise yin ma gba coodu ti e ba ra aiye oruko .WED l’odoodun pelu coodu yi, e ko ni san owo odun keta-ewa. A ma ye iwe wo lati wo yi l’odoodun.
E le ra aiye oruko .WED ni ipo keta (fun apere, myweddingbusiness.planner.wed abi myweddingbusiness.officiant.wed) fun to odun mewa.

Iru nkan wo ni e le se ni aiye .WED?
- E e le ra paaji lati tunta.
- E e le ra paaji lati p’olowo oja.
- E e le han eyan ti o n se isekuse.
- E e le bu eyan nitoru ilu, awo, ara ibi ti won wa, eni ti won fe, ise ti won se ati be lo.
- E e le ta iyawo.
- E e le ta omode fun iyawo.
- E e le eyan.
Se mo le ta aiye oruko .WED mi?
Eyan o le ra oruko .WED fun tita nikan sugbon eyan le ta fun owo kanaa ti eyan fi koko ra oruko yen. Eyan o le ta oruko .WED no okson.
Bawo ni ma royin eni ti o gba liana for lilo oruko .WED?
E koi we email pelu akiyesi yi si abuse@atgron.wed Atgron, Inc. 9435 Lorton Market St., Lorton, VA 22079 Attn: Abuse Dept . Ilokulo .WED le je ki a da oruko naa duro lai ma fun eyan no owo pada ti a ba rip e nkan yi sele ni tooto.
Bawo ni a se ma mo bi oruko .WED mi wa fun rira?
E ko oruko ti e fe si website ki e to ra lowo Rejistra.
Bawo ni mo se le paro ibi ti website mi was fun aiye orulo .WED mi?
Aiye oruko papo pelu website ni nameservers. Ati paro nameservers ko soro.
1. E ra website lati ile ise tuntun ki e de gba nameserver.
2. E log si ile ise ibi ti e ra aiye oruko yin.
3. E paro nameserver si ti website tuntun ti e fe lo.
4. E duro fun igba die abi ojo kana bi meji fun piparo yen lati sele.
5. E so fun ile ise website tuntun ti e lo pelu oruko .WED yin fun nameserver e de ma ri oruko yin ni iwe ile ise won.
E le se yi li ma paro oruko .WED sugbon ti e ba san owo website ni odo ile ise kan ki ewa lo si ile ise imii e le ma gba owo yin pada ati pe e ma ni lati tun website yin se tabi ki e bere imi ti o le soro.