Ra .WED :
Iwulo aiye
.WED:
1) Oro foonu ti o po ati aiye pupo ati gbadun ebi ati ore.
2) Adiresi ero araaya ti o gun ju ati ti eniyan le tete wa - www.iwoatiokoabiyawo.WED.
3) E kedee oro igbeyawo yin ni gbangba abi n'ile; eyin ni e ni aiye yen.
4) Ko si wahala mo, oruko aiye yin ni tiyin nikan.
5) E tete kedee eto igbeyawo yin pelu ero.

Sun s'egbe .COM, .WED ti n bo
Ni odun 2014, ero ayara ma yato. 1000 Aye ero ayara to da ma jade ni odun ti o n bo ni ICAAN ero ayaara tuntun (gTLD) lati ni aiye ero ayaara tuntun fun awon eniyan. .COM, .ORG, .NET, .BIZ ati coodu ilu ko ni je soosoo ni oja.
E reti .WED, aye ero ayaara tuntun ti o ma fun pupo awon toko taya ni aiye ero ayaara to won fe. Won o ni lati lo aiye ero araaya pelu .COM to won o fe, tabi ti o gun ju lati elo mi. A ma ta aiye oruko .WED fun toko taya fun odun kan abi meji lati se ajoyo igbeyawo won. Ni eyin igba yi, a ma lo aiye aruko yi fun toko taya imi.
E ro bi o se ma a ri ki e ni aiye tiyin fun ojo rere tiyin. Ayo ati Ade le ni AyoatiAde.WED, ati pe Ayo ati Ade imi le ni AyoatiAde.WED ni odun kan tabi meji t’on bo. A a n pe ni ife ti kii tan:-) A fe ki e ni aiye ti o da ju fun ojo ti o pataki fun yin.
.WED se nkan tuntun fun aiye oruko ni bi oti se dara fun took taya. Kaka ki e lo aiye ero araaya lehin odun meji, e le lo aiye oruko yin fun omo bibi (AyoatiAde.Omo.WED) tabi ki e toju .WED yin ju odun meji lo.
E le ra aiye oruko .WED ni ona keta (fun apeere Ade feran Ayo.titilailai.wed) fun to odun mewa. Ona keta yi maa je ki e le so fun ara ati ore ni ile tabi ni gbangba ni nkan ti o n sele ni igbesi aye yin fun odun pupo.
E gba ibi fun Ibeere .WED